Àwọn ìṣáájú
- dis – pínyà, túká
- ek – ìbẹ̀rẹ̀ ìṣe, lojijì
- for – kúrò, sọnù
- ge – akọ àti abo papọ̀
- mal – òdì
- re – lẹ́ẹ̀kansi, padà
Àwọn àfikún
- ad – ìṣe tó ń tẹ̀síwájú
- an – ọmọ ẹgbẹ́
- ar – akojọpọ̀
- aĉ – ànímọ́ búburú
- aĵ – nǹkan, ohun tó hàn gbangba
- ebl – ṣeé ṣe
- ec – àbùdá àfojúsùn
- eg – ńlá, pọ̀ gan-an
- ej – ibi
- er – apá kékeré, ẹ̀ka
- estr – olórí, adarí
- et – kékeré, díẹ̀
- ig – mú kí ó di
- il – irinṣẹ́, ọ̀nà
- in – abo
- ind – tó yẹ fún
- ist – iṣẹ́, ẹni tó máa ń ṣe ohun kan
- iĝ – di
- uj – apoti, igi, orílẹ̀-èdè
- ul – ẹni
- um – ìtumọ̀ aláìdájú