Reklamo: Venu al la Universala Kongreso en 🇦🇹 Aŭstrio, 1–8 aŭg. 2026

Nínú ọ̀rọ̀

  • Marko – Marko
  • esti – jẹ́, wà
  • as – Ọ̀rọ̀-ìṣe àkókò ìsinsin yìí
  • mi – èmi
  • a – Àjẹtífù
  • amiko – ọ̀rẹ́
  • o – Orúkọ-nǹkan
  • li – òun akọ
  • lerni – kọ́ ẹ̀kọ́
  • ant – olùṣe lọwọlọwọ
  • kaj – àti
  • sporto – eré ìdárayá
  • ist – iṣẹ́, ẹni tó máa ń ṣe ohun kan
  • nun – báyìí
  • sidi – jókòó
  • en – nínú
  • ĉambro – yàrá
  • sur – lórí
  • tablo – tábìlì
  • papero – bébà
  • j – Púpọ̀
  • libro – ìwé
  • ĝi – ó
  • skribi – kọ
  • la – náà
  • patro – bàbá
  • in – abo
  • de – ti, láti
  • ne – rárá, kò
  • ili – àwọn
  • labori – ṣiṣẹ́
  • hotelo – hòtẹ́lì
  • instrui – kọ́ni
  • ŝi – òun abo

Sí i

  • Ana – Ana
  • ĉu – ṣé
  • jes – bẹ́ẹ̀ ni
  • kio – kí ni
  • kiu – ta ni, wo ni
  • lingvo – èdè
  • ni – àwa
  • nomo – orúkọ
  • respondi – dáhùn
  • seĝo – àga