Nínú ọ̀rọ̀
- letero – lẹ́tà
- vera – òtítọ́
- foto – fọ́tò
- kiam – nígbà wo
- re – lẹ́ẹ̀kansi, padà
- el – láti inú, jáde kúrò nínú
- rapida – yára
- tie – níbẹ̀
- stari – dúró
- Vera – Vera
- mano – ọwọ́
- koleri – ìbínú
- iĝ – di
- ruĝa – pupa
- fali – ṣubú
- pardoni – dárí jì
- doni – fún
- ricevi – gbà
- leciono – ẹ̀kọ́
- plu – síwájú, mọ́
- os – Ọ̀rọ̀-ìṣe ọjọ́ iwájú
- devi – gbọdọ̀
- fermi – pa
- pordo – ilẹ̀kùn
Sí i
- aŭdi – gbọ́
- ĉe – ní ọ̀dọ̀
- dek – mẹ́wàá
- du – méjì
- for – kúrò, sọnù
- inter – láàárín, ní àárín
- kapo – orí
- kiom – mélòó
- kien – síbo
- kvar – mẹ́rin
- kvin – márùn-ún
- lasta – kẹ́yìn
- meti – fi
- nacio – orílẹ̀-èdè, ẹ̀yà
- naŭ – mẹ́sàn-án
- ok – mẹ́jọ
- piedo – ẹsẹ̀
- poŝo – àpò
- preni – mú
- ses – mẹ́fà
- sep – méje
- sia – tirẹ̀ fúnra rẹ̀, tiwọn fúnra wọn
- sola – nìkan
- trankvila – balẹ̀
- tri – mẹ́ta