Nínú ọ̀rọ̀
- sinjoro – ọ̀gbẹ́ni, ọkùnrin ọlọ́lá
- vendi – tà
- aŭto – ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́
- kiu – ta ni, wo ni
- plaĉi – dùn mọ́ni
- demandi – béèrè
- plej – jùlọ
- tiu – ẹni yẹn, ìyẹn
- ĉi – yìí
- ĉiu – gbogbo ènìyàn, olúkúlùkù
- pli – ju bẹ́ẹ̀ lọ, díẹ̀ sí i
- ol – ju
- tre – gan-an
- certa – dájú
- kosti – jẹ́ owó
- bedaŭri – bínú sí
- ind – tó yẹ fún
- aĉeti – rà
- ĉar – nítorí, torí pé
- veturi – rìn pẹ̀lú ọkọ̀
- dum – nígbà
- tio – ìyẹn
- edzo – ọkọ
Sí i
- aŭskulti – gbọ́
- forgesi – gbàgbé
- helpi – ràn lọ́wọ́
- horo – wákàtí
- jam – tẹ́lẹ̀
- jaro – ọdún
- kial – kí ló dé
- komenci – bẹ̀rẹ̀
- monato – oṣù
- plena – kún
- sendi – fi ránṣẹ́
- tempo – àkókò
- vivi – wà láàyè