Reklamo: Venu al la Universala Kongreso en 🇦🇹 Aŭstrio, 1–8 aŭg. 2026

Túmọ̀ kí o sì dáhùn

1. Nígbà wo ni màá tún rí ọ?

2. Báwo ni o ti pẹ́ tó tí o ti ń kọ́ Èdè Àgbáyé?

3. Níbo ni ìwé tuntun mi pẹ̀lú àwọn fọ́tò wà?

4. Síbo ni o máa lọ lẹ́yìn oúnjẹ ọ̀sán?

5. Ṣé a lè pa ilẹ̀kùn yàrá náà nígbà tí òtútù bá ń mú?

6. Báwo ni o ṣe máa ń bínú pẹ́ tó bí ènìyàn bá gba owó púpọ̀ lọ́wọ́ rẹ?