Reklamo: Venu al la Universala Kongreso en 🇦🇹 Aŭstrio, 1–8 aŭg. 2026
  ki-
ìbéèrè
ti-
ìtọ́ka
i-
àìdájú
ĉi-
gbogbo
neni-
ìkọ̀
-o
nǹkan
kio
kí ni
tio
ìyẹn
io
nǹkan kan
ĉio
gbogbo nǹkan
nenio
kò sí nǹkan
-u
ẹni tàbí ohun pàtó
kiu
ta ni, wo ni
tiu
ẹni yẹn, ìyẹn
iu
ẹnì kan
ĉiu
gbogbo ènìyàn, olúkúlùkù
neniu
kò sí ẹnikẹ́ni, kò sí ọ̀kan
-am
àkókò
kiam
nígbà wo
tiam
nígbà yẹn
iam
nígbà kan
ĉiam
nígbà gbogbo
neniam
rárá nígbà kankan
-a
àbùdá
kia
irú wo
tia
irú bẹ́ẹ̀
ia
irú kan
ĉia
gbogbo irú
nenia
kò sí irú kankan
-e
ibi
kie
níbo
tie
níbẹ̀
ie
ibì kan
ĉie
níbi gbogbo
nenie
kò sí ibì kankan
-el
ọ̀nà
kiel
báwo
tiel
bẹ́ẹ̀
iel
lọ́nà kan
ĉiel
ní gbogbo ọ̀nà
neniel
kò sí ọ̀nà kankan
-om
iye
kiom
mélòó
tiom
tó bẹ́ẹ̀
iom
díẹ̀, iye kan
ĉiom
gbogbo rẹ̀, gbogbo iye náà
neniom
kò sí díẹ̀ rárá, iye kankan kò sí
-al
ìdí
kial
kí ló dé
tial
nítorí ìyẹn
ial
fún ìdí kan
ĉial
fún gbogbo ìdí
nenial
láìsí ìdí kankan
-es
ìní
kies
ti ta ni
ties
ti ẹni yẹn
ies
ti ẹnì kan
ĉies
ti gbogbo ènìyàn
nenies
ti ẹnikẹ́ni kò sí